Kilode Ti O Ma Nfo Owo Re?

Why Do You Wash Your Hands? in Yoruba and English.

Ójẹ ọ̀nà tí kó ná ní lówó tí ó sí wú ló púpọ̀ lati sé itọjú ara dádá.
KÍLÓDÉ TI Ó MÁ NFỌ ỌWỌ RẸ? Jé ọ̀ná ídárá yá láti kọ́ ọmọdé ní pàtàkí ọwọ́ f́ifọ́. Pẹlu àwòrán tí ó jọjú atí èdè tí kó lé, ọmọdé ma fẹ́ látí ka iwé yì atí látí kó awón àwòrán tí ofá ní mó ra lẹyín itán náà jọ.

Book Reviews